IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 18 February 2016

Minista Ngige daku nileegbimo asofin apapo

Minista fun oro awon osise ati igbanisise lorileede yii, Dokita Chris Ngige la gbo pe o daku niwaju awon igbimo to n ri si oro ise nile igbimo asofin apapo.
Lasiko to n salaye lori akosile eto isuna ileese re nisele naa sele, ti won si gbe e digbadigba lo sileewosan funtoju.

No comments:

Post a Comment