Leyin ose meji ti gomina egbe oselu APC gbajoba nipinle Kogi, won ti ye aga mo Momoh Jimoh Lawal to je abenugan ile igbimo asofin ipinle naa to je omo egbe oselu PDP nidi.
Bakan naa ni won tun yo igbakeji abenugan, Aliu Ajuh ati olori omo ile to poju, Kolawole Matthew.
Sugbon Momoh Lawal so pe ala ti ko lee se ni.

No comments:
Post a Comment