IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 17 March 2016

Asofin ipinle Ekiti ti ku sahamo awon otelemuye l'Abuja o

Okan lara awon omo ile igbimo asofin ipinle Ekiti to wa lahamo awon otelemuye, DSS lati ojo kerin osu keta odun yii la gbo pe o ti ku bayii.
Gege bi komisanna feto iroyin nipinle Ekiti se so, ale ana ni Onarebu Afolabi Akanni to n soju awon eeyan agbegbe Efon bere aisan latari aifaaye gba awon dokita re atawon molebi lati rii, o si jade laye laaro oni.

No comments:

Post a Comment