IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 15 September 2016

Audu Ogbeh so pe ajeju iresi le sakoba faraa wa

Minista foro eto ogbin lorileede yii, Oloye Audu Ogbeh ti so bombu oro, o ni ajeju iresi ni akoba to n se faraa wa.
Lasiko yi ti apo iresi kan ti di egbern lona mejilelogun naira, to si je pe ounje kansoso teeyan ko le saibapade ninu opolopo ile lorileede yii bayii ni iresi, Audu ni se ni ka wa ounje miin lati maa je, ka si juwo si iresi.
E oo ranti pe igbakeji re, Heinneken Lokpobiri so lose to koja pe afaimo ki apo iresi kansoso ma di egberun lona ogoji naira ki odun yii too pari.

No comments:

Post a Comment