Bi kii ba se ti awon olopa RRS nipinle Eko ti won tete da si oro naa laaro oni, boya ogun abele iba ti be sile nipinle Eko bayii.
Ohun ti a gbo ni pe awon Fulani atawon Hausa ni won koju ija siraa won ni odo -eran kan to wa ni Agege, kawon eean si too mo nnkan to n sele, hausa kan ti je Olorun nipe.
Ko seni to mo ohun to da wahala naa sile, se ni kaluku bere sii sa lugbo nigba ti wahala naa bere titi di igba tawon olopa debe.
Wednesday, 7 September 2016
Awon Fulani koju ija sawon Hausa l'Eko, ni won ba gbemi Hausa kan
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment