IROYIN YAJOYAJO

Sunday, 18 September 2016

Idi ti ipinle Ekiti fi se ipo kinni ninu esi idanwo NECO

Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Fayose ti so pe ipa takuntakun ti oun n ko lori oro eto eko nipinle Ekiti, ti oun ko si fowo yepere mu oro awon oluko lo sokunfa bi ipinle naa se gbe igba oroke ninu esi idanwo NECO ti won gbe jade laipe yii.
Ipinle Ekiti lo se ipo kinni, ipinle Edo wa ni ipo keji, nigba ti ipinle Abia wa ni ipo keta ninu esi idanwo naa.

No comments:

Post a Comment