IROYIN YAJOYAJO

Sunday, 18 September 2016

Nipinle Ekiti, Abdullahi yinbon lu elede, niyen ba yipada di ore e

Ile ejo majistreei kan nilu Ado-Ekiti ti pase pe ki won loo fi okunrin olode kan, Ganiyu Abdullahi pamo sogba ewon lori esun pe o pa elede to yipada di oree re, Iginla Oluwashina.
Ojo kesan osu kesan odun yii nisele naa sele ni Iwaraji nitosi Efon-Alaaye nipinle Ekiti.

No comments:

Post a Comment