IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 29 September 2016

Sir Etim, oga agba tele funleese olopa ti jade laye

Oga agba funleese olopa orileede yii nigba kan, Sir Etim Okon Inyang ti jade laye leni odun marundinlaadorun.
Ileewosan kan nipinle Eko la gbo pe baba yii, eni to dari awon olopa
laarin odun 1984 si 1986 dake si.

No comments:

Post a Comment