Mokanlelogun ninu awon omobinrin ileewe Chibok tipinle Borno ti awon iko Boko Haramu ji ko lodun 2014 ni won ti tu sile bayii.
Nidaji oni la gbo pe awon omo ologun ri awon omobinrin naa lagbegbe Banki nipinle Borno nibi ti awon boko haramu ja won si.
Thursday, 13 October 2016
Awon Boko Haram ti tu mokanlelogun sile ninu awon omoleewe Chibok
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment