Tolulope Emmanuel, Osogbo
Lara ona lati se koriya fawon osise ijoba nipinle Osun, Gomina Aregbesola ti kede oruko awon osise mokanla ti won se daada ju losu ti a wa yii.
Gege bi atejade lati ofiisi olori awon osise ijoba se so, awon mokanla ti won pegede lati gba awoodu ohun niwonyii:
Ogbeni Oseni Asifatu lati State Water Corporation, Ogbeni Akeem Raji, Osun
Education Quality & Morality Enforcement Agency, Mr. Ibrahim Akinwale
Morufu, Osun Tourism Board ati Mr. Abiodun Akanbi lati Ministry of
Information and Strategy.
Awon yooku ni Ogbeni Samson Adeniyi Alake, State of Osun
Property Development Corporation, Mrs. Toyin Oyewumi, Ministry of
Lands and Physical Planning ati Mr. Mukaila Adeboye lati Ministry of
Women, Children and Social Affairs.
Bakan naa la ri Mr. Dada Oparinde ti'Ministry
Commerce, Industry and Cooperatives, Mrs Grace Adeyoola, Ministry of
Innovation, Science and Technology, Mrs Margret Banke Olanrewaju ti Culture and Tourism ati Moshood Sulaiman latileese igbohunsafefe OSBC.

No comments:
Post a Comment