IROYIN YAJOYAJO

Saturday, 11 November 2017

E wo foto ayeye igbeyawo omo Ajimobi ati omo Ganduje nipinle Kano






Fofo ni aafin Emir ti ilu Kano, Muhammadu Sanusi 11 kun loni nigba ti awon gomina ko araa won jo lati loo ba omokunrin kansoso ti gomina ipinle Oyo, Seneto Abiola bi toro okan lara awon omobinrin gomina ipinle Kano.

Abolaji Idris Ajimobi ati Fatima Umar Ganduje ni won fonte lu ife aarin won loni.

Lara awon ipinle ti gomina won lo ni ipinle Osun, Katsina, Eko, Ogun, Kwara ati bee bee lo.

No comments:

Post a Comment