Bo tile je pe awon egbe osise nipinle Kaduna ti ni awon ko nii faramo bi gomina ipinle naa, Nasir el-Rufai se da awon oluko ileewe alakobere egberun lona mokanlelogun duro, sibe gbogbo awon ti won ti ri esi idanwo tijoba se fawon oluko naa ni won n so pe ijoba ko lebi rara.
Idanwo awon omo kilaasi kerin nileewe alakobere ni won gbe fawon oluko naa sugbon arifowoboju ni idahun tawon oluko naa ko sile.
Idi niyen ti gomina fi so pe ti awon ti won n ko awon omo ba ya olodo bee, a je pe wahala wa fun ojo ola ipinle naa.
E wo ibeere ati idahun awon oluko ohun:









No comments:
Post a Comment