IROYIN YAJOYAJO

Sunday, 12 November 2017

Wahala wa o ! E wo leta igbanisise ti oluko kan tun ko ni Kaduna


Laipe yii ni gomina ipinle Kaduna, Nasir el-Rufai kede dida oluko egberun mokanlelogun duro latari bi won se fidi remi ninu idanwo tijoba se fun won.

Gomina waa pase fun ajo UBEB ipinle naa lati gba awon oluko tuntun sawon ileewe alakobere ohun.

Sugbon iyalenu lo tun je lati ri iwe igbanisise ti enikan tun ko, idi niyii tawon eeyan fi n so pe kini yoo je ona abayo si wahala naa bayii.

Leta naa niyii:

No comments:

Post a Comment