Iyalenu lo je fun awon olugbe ilu Uyo nipinle Akwa Ibom laipe yii nigba ti Pasito ijo kan ti a foruko bo lasiri dede ko awon ike omi ti nnkan pupa wa ninu e jade, to si so fawon omo ijo re pe 'eje Jesu' lo wa ninu ike naa.
Pasito yii la gbo pe o ni egberun meji naira ni okookan eje inu ike naa ati pe ohun gbogbo ti won ba ti lo o fun ni won yoo ri idahun si.
Lara awon omo ijo naa ti ko daruko ara re so pe warawara ni eje naa n sise ati pe agbara nla wa ninu e niwon igba tawon ba ti le ri egberun meji naira tawon yoo fi ra a.
No comments:
Post a Comment