Lẹyin oṣẹ meji ti Poopu tẹlẹ fun ijọ Aguda dagbere faye, wọn ti kede Cardinal Robert Prevost gẹgẹ bii poopu tuntun fun ijọ Katoliiki bayii.
Prevost fitan balẹ gẹgẹ bii ọmọ orileede Amẹrika ti yoo kọkọ jẹ poopu lati nnkan bii ẹgbẹrun ọdun meji sẹyin.
Ọmọ ọdun mọkandinlaadọrin ni, Leo XIV lo si gba pe oun fẹẹ maa jẹ.
No comments:
Post a Comment