IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 23 August 2017

Aheso lasan ni o, gidigba ni baba mi wa - Yemi Olaiya

Okan lara awon omo gbajugbaja alawadaa ni, Moses Olaiya ti gbogbo eeyan mo si Baba Sala ti so pe ko si ooto kankan ninu aheso to n lo kaakiri bayii pe baba oun ti jade laye.
Yemi Olaiya, eni to soro ni nnkan wakati mewa seyin so pe oun ati baba oun si soro ni wakati die seyin sigba yen ati pe ko ko ko lara ota baba oun le.
Omo odun mejilelogorin ni Baba Sala to je omobibi ilu Ilesa ohun.

No comments:

Post a Comment