IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 30 August 2017

E ba mi so fun Amosun ko sanwo gba-ma-binu fun mi lori ile mi o - Rotimi Makinde

Gbajugbaja osere tiatia ile Yoruba to tun ti figba kan je asofin to soju awon eeyan agbegbe Ife, Honorebu Rotimi Makinde ti ke gbajare sita pe gomina ipinle Ogun, Seneto Ibikunle Amosun ko lati fun oun lowoo gba-ma-binu lorii ile toun ko sipinle naa to fee wo.
Laipe yii nijoba ipinle Ogun sami si ilee Makinde pe ona fee gba ibe koja, awada ni gbogbo eeyan koko pe oro naa sugbon oro naa ti n di tooto bayii.
Ero okan Makinde ni pe Gomina Amosun yoo sanwo fun un sugbon pabo ni gbogbo igbiyanju ati ireti re jasi.
Idi niyii ti Makinde fi pariwo sita pe gbogbo nnkan toju oun ti ri nidi oselu ti po ju kijoba Amosun tun da kunsoro oun lo.

No comments:

Post a Comment