IROYIN YAJOYAJO

Saturday, 30 September 2017

E wo die lara awon tokotaya ti won n se daada ninu fiimu ile wa

Rafiu Balogun ati Fausat Balogun ti gbogbo eeyan mo si Madam Saje

Sunday Adewale to je oludari fiimu ati Toyin Adewale

Afeez Owo ati Mide Martins Owo

Lukman Raji (King of swagga) atiyawo re, Bukky Adekongbe ti gbogbo eeyan mo si Aminatu Papapa


Damola Olatunji ati Bukola Awoyemi (Arugba)

1 comment: