IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 28 September 2017

Ope oo! Won ti kede Elegboro ti Ijebujesa

Gomina ipinle Osun, Ogbeni Aregbesola ti kede Omooba Femi Agunloye gege bii Elegboro ti Ijebu-Ijesa.
Ipo naa si sile leyin Oba to wa nibe tele darapo mo awon babanla re.
Ninu leta kan ti oga agba nileese ijoba ibile ati oye jije, Ogbeni Femi Ogundun fowosi ni iyansipo Agunloye wa nibamu pelu abala ogun ofin oye jije ti odun 2002.

No comments:

Post a Comment