Woli to so nipa bijoba yoo se bo lowoo Aare Goodluck Jonathan lodun 2015 tun ti ju bonbu oro miin bayii.
Woli Onyekachukwu Okolie to je oludasile ati alakoso ijo Living Abundance (Mount Zion) Prophetic and Deliverance Ministry lo tun ti so pe enikan lati eya Yoruba loun ri ti yoo di aare orileede yii lodun 2019.
Okolie ni Olorun ti fi han oun pe Aare Mohammed Buhari yoo saseyori ijoba to n ba lo yii sugbon ko nii dupo lati se saa keji.
O ni kidibo odun 2015 too bere loun ti rii kedere pe Jonathan yoo fidi remi patapata eleyii to si wa simuse.
O waa ni ki gbogbo awon eeyan ko o sile pe oun tun ti so bayii pe eya Yoruba ni yoo di aare orileede Naijiria lodun 2019
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment