Tolulope Emmanuel, Osogbo
Oludije kan funpo gomina nipinle Osun, Dokita Benedict Olugboyega Alabi (BOA) ti so pe owo to n wole labenu funjoba ipinle Osun le rugogo sii bijoba ba le pinnu lati samojuto ise agbe.
Adegboyega, eni to n gbaradi lati dije labe egbe oselu APC salaye pe ise agbe to lati mu nnkan pada bosipo funjoba, bee lo ni sise agbedide awon ibudo asa kaakiri korokondu nipinle yii yoo tun fokan ijoba bale lori owo to n wole.
O waa seleri fun gbogbo awon osise ijoba ati awon osisefeyinti pe bii eera inu suga ni won a maa yo toun ba di gomina nipinle Osun.
O nii kii se awada ni erongba oun lati di gomina, bee ni kii se fun idunadura pelu enikeni.
BOA, omobibi ilu Ikire so pe erongba oun ni lati tesiwaju ninu awon ise ribiribi tijoba Gomina Aregbesola ti dawole ni kete toun ba ti gba eeku ida.
Friday, 13 October 2017
Amojuto ise agbe lo le mu iyipada otun ba wa l'Osun - BOA
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment