IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 4 October 2017

L'Ekiti, aadota oludije jade funpo gomina, e wo oruko won


Tolulope Emmanuel

Bi idije funpo gomina ipinle Ekiti se ku feerefe bayii, aadota oludije lo ti fife han lati gbapo ohun lowoo Gomina Ayodele Fayose.

Ninuu won, eeyan mokanlelogoji lo wa latinu egbe oselu APC, eeyan mefa wa latinu egbe oselu PDP, nigba ti eeyan kan wa latinu egbe UNDP, ti egbe MPN si ni oludije meji.

Oruko awon oludije ohun niyii:

1. Kola Alabi - APC
2. Oluwole Oluyede - APC
3. Olufemi Bamisile - APC
4. Prof. Kolapo Olusola-Eleka - PDP
5. Bimbo Daramola - APC
6. Bamidele Faparusi - APC
7. Makanjuola Owolabi - APC
8. Gbenga Aluko - APC
9. Segun Oni - APC
10. Muyiwa Olumilua - APC
11. Adedayo Adeyeye - PDP
12. Biodun Olujimi - PDP
13. Segun Adewale - PDP
14. Olumuyiwa Coker- APC
15. Victor Kayode - APC
16. Kayode Ojo - APC
17. Sunday Adebomi - APC
18. Owoseeni Ajayi - PDP
19. Dare Bejide - PDP
20. Adekunle Esan - APC
21. Bayo Ogunkayode - APC
22. Segun Agbalajobi - APC
23. Adebayo Orire - APC
24. Ishola Fapounda - APC
25. Diran Adesua - APC
26. Folorunsho Akinyele - APC
27. Dele Okeya - APC
28. Femi Ojudu - APC
29. Ayo Arise- APC
30. Musa Ayeni - UNDP
31. Opeyemi Bamidele - APC
32. Sesan Fatoba - APC
33. Funminiyi Afuye - APC
34. Bayo Idowu - APC
35. Bisi Aloba - APC
36. Bodunde Adeyanju - APC
37. Kayode Adaramodu - APC
38. Abiodun Aluko - MPN
39. Bode Olowoporoku - MPN
40. Bayo Babalotin - APC
41. Yinka Akerele - APC
42. Kole Ajayi - APC
43. Debo Ranti - APC
44. Kayode Oladipupo - APC
45. Temitope Adebayo - APC
46. Prof. Omoniyi Adetiloye - APC
47. Femi Thomas - APC
48. Olajide Akinyemi - APC
49. Oluwole Oluleye - APC
50. Jide Johnson - APC

1 comment:

  1. Wahala ti ani lorilede yi ni pataki julo nipe 'oselu je ola ojiji' idi niyi ti Ryan ni adota se ndu ipo gomina lekiti. Kayefi gba ni

    ReplyDelete