Tolulope Emmanuel
Ooni tilu Ileefe, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti so pe kii se nnkan to dara bi awon kan se n pe awon odo to n ja fun idasile orileede Biafra eleyii ti Nnamdi Kanu n dari ni egbe agbesunmomi.
Oba Adeyeye ni dipo Indigenous People of Biafra ti won n je, ojulowo oruko won ni Indigenous People of Brighter Nigeria (IPOBN).
Lasiko ti Kabiesi loo ba awon eeyan ipinle Abia yo ayo odun isu tuntun lo soro naa lodo Gomina Okezie Ikpeazu.
O ni awon eeyan ohun ni nnkan to n dun won, bee ni nnkan kan lo n pa won lekun, ko waa ye ka ta won nu bikose kipade apero wa lorii won nibi ti won yoo ti so edun okan won.
Ooni ni 'a ko gbodo ta won nu, a gbodo fa won mora ni, awon odo ni ojo ola orileede yii, awon ni agbara wa.
"Ti a ba fa won mora, ti a jo so oro asoyepo, a maa lanfaani lati lo agbara ati ogbon won fun idagbasoke ti ko legbe lorileede yii, won kii se egbe agbesunmomi, eto won ni won n ja fun, won si to si idajo ododo pelu'.
Saturday, 7 October 2017
Ogbon agba! Ooni yi oruko IPOB pada, e ka nnkan to pe won
Tags
# iroyin
# iroyin-agbegbe
.Unknown
.
iroyin-agbegbe
Labels:
iroyin,
iroyin-agbegbe
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Agba onitan lorile
ReplyDelete