IROYIN YAJOYAJO

Friday, 6 October 2017

Ife bi eji owuro! E ka nnkan ti Mosun Filani so nipa oko re, Super Kay




"O ku ayeye ojo ibi re, ife mi, oko mi, egbon mi, ore mi, alafokantan mi, enikansoso ti mo ni, ejika ti ko je ki orun o bo, oluko mi, baba mi, ohun gbogbo fun mi... Bi o se n sajoyo odun miin loni, Olorun a mu gbogbo erongba okan re wa simuse, wo a maa dagba ninu ilera pipe ati oro, wa se oko fun mi dale, wa se baba fun awon omo wa dale. Niwoyi amodun.....Ololajulo loruko Jesu. Mo nifee re, mo si nifee re, bee ni maa si tun maa nife re si!!!

No comments:

Post a Comment