Ajo to n ri si eto idibo ijoba ibile nipinle Osun, Osun State Independent Electoral Commission (OSIEC) ti kede ojo ketadinlogbon osu kinni odun 2018 gege bii ojo idibo l'Osun.
Ninu ipade kan ti alaga ajo naa, Otunba Segun se pelu awon asoju egbe oselu ti won ti forukosile lati kopa nibi eto naa ni won ti fenuko si ojo yii.
Egbe oselu metadinlogoji nireti wa pe won yoo kopa nibi idibo ohun, gbogbo won si ti seleri lati huwa omoluabi saaju ati lasiko idibo ohun.

No comments:
Post a Comment