Tolulope Emmanuel
Iya lo ba de fun egbe agbaboolu Chipolopolo ti orileede Zambia loni nigba ti egbe agbaboolu ile wa, Super Eagles gbo ewuro si won loju.
Ipinle Akwa Ibom nidije naa ti waye nirole oni nibi ti Alex Iwobi ti ju ayo kan wole ti awon araa Zambia si n wo duu.
Ikogoja yii lo fun Super Eagles lanfaani lati kopa nibi idije boolu agbaye ti yoo waye lorileede Russia lodun to n bo.
Saturday, 7 October 2017
Super Eagles fi Chipolopolo se ategun lo si Russia
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment