Tolulope Emmanuel
Loooto lawon egbe oselu maa n seleri orisiirisi lasiko ipolongo idibo lorileede yii sugbon ijakule loroo won maa n je nigba ti oludije won ba dori aleefa.
Iwadi ti fihan bayii pe opolopo awon eeyan yii ni ojo-ori won ko gba won laaye lati mu opolopo ileri won se.
Lowolowo bayii, awon mewa ni won ti le ni ogota odun lara awon gomina ti won wa kaakiri ipinle lorileede yii, ko si eegun ise mo, bee ni o niwonba nnkan ti won le gbe sori.
Abajo ti awon odo kan se n pariwo pe enikeni to ba ti le laadota odun ko to sipo oselu mo lorileede yii nitori won ko nii ni eegun lati sise mo.
Bi a ba n soro nipa iriri, ko si nnkan to buru bi awon agbaagba yii ba n fi iriri ati ogbon won ti awon odo ti won ba wa nipo oselu leyin.
Akojopo ojo ori awon gomina lorileede yii fi han pe gomina ipinle Oyo, Seneto Abiola Ajimobi lo dagba ju, o si ti sunmo omo odun aadorin.
E wo ojo ori awon gomina ohun:
Oyo – Abiola Ajimobi 16/12/49 67yrs
Kano – Abdullahi Ganduje 25/12/49 – 67yrs
Katsina – Aminu Masari 29/05/50 – 67yrs
Nasarawa, Umaru AlMakura 15/11/53 – 63yrs
Taraba, Darius Ishaku 30-Jul-54 63yrs
Ondo, Oluwarotimi Akeredolu 21/07/56 61yrs
Yobe, Ibrahim Geidam 15/09/56 – 61yrs
Bauchi, Mohammed Abubakar 11/12/56 – 60yrs
Osun, Rauf Aregbesola 25/05/57 – 60yrs
Anambra, Willie Obiano 08/08/57 – 60yrs
Ogun, Ibikunle Amosun 25/01/58- 59yrs
Edo, Godwin Obaseki 01-Jul-59 58yrs
Delta, Ifeanyi Okowa 08-Jul-59 58yrs
Kaduna, Nasir El-Rufai 16/02/60 – 57yrs
Ekiti, Ayodele Fayose 15/11/60 – 56yrs
Benue , Samuel Ortom 23/04/61 – 56yrs
Kebbi, Abubakar Bagudu 26/12/61 – 55yrs
Gombe, Ibrahim Dankwambo 04/04/62 – 55yrs
Imo, Rochas Okorocha 22/09/62 – 55yrs
Jigawa, M Badaru Abubakar 29/09/62 – 54yrs
Plateau, Simon Lalong 05-May-63 54yrs
Lagos, Akinwunmi Ambode 14-Jun-63 54yrs
Adamawa, Bindo Jibrilla 16-Jun-63 54yrs
Kwara , Abdulfatah Ahmed 29-Dec-63 53yrs
Ebonyi, Dave Umahi 01-Jan-64 53yrs
Enugu, Ifeanyi Ugwuanyi 20-Mar-64 53yrs
Abia, Okezie Ikpeazu 18-Oct-64 52years
Sokoto, Aminu Tambuwal 10-Jan-66 51yrs
Bayelsa , Seriake Dickson 28-Jan-66 51yrs
Akwa Ibom , Udom Emmanuel 11-Jul-66 51yrs
Borno, Kashim Shettima 02-Sep-66 51years
Rivers , Nyesom Wike 24-Aug-67 50yrs
Niger, Abubakar Bello 17-Dec-67 49yrs
Zamfara , Abdulaziz Yari 01/01/69 – 48yrs
Cross River, Ben Ayade 02/03/69 – 48yrs
Kogi , Yahaya Bello 18/06/75 – 42yrs
Afi ki awon odo dide lati gba akoso orileede yii kuro lowo awon arugbo ti won n se nnkan to wu won lori aleefa.
No comments:
Post a Comment