Gomina ipinle Cross River, Ben Ayade ti pase pe won ko gbodo gbadura ni gbogbo awon ileewe tijoba ati ti aladani to wa kaakiri ipinle naa mo.
Ninu leta kan ti akowe agba funleese to n ri si eto eko nipinle naa, Iyaafin Anne O. Odey fowosi lo ti salaye pe ileewe to ba tapa si ase naa yoo fimu danrin.
Sugbon alaga egbe awon onigbagbo, CAN nipinle naa, Archbishop J.E. Ukpo so pe igbese ijoba naa lewu lopolopo fun ojo ola ipinle Cross River.
Friday, 30 October 2015
Gomina Ben Ayade ni won ko gbodo gbadura nileewe mo
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment