IROYIN YAJOYAJO

Tuesday, 20 October 2015

L'Akungba-Akoko, were odun mejidinlogun san niwaju soosi

Se ni Musa Saheed to ti ya were lati odun un 1997 n koja niwaju soosi kan ti won ti n gbadura laipe yii ti iye re fi si, ti were araa re si di ohun igbagbe.
Omobibi ilu Ibadan ni Musa sugbon gbajugbaja were ni nilu Akungba-Akoko, iwaju ile nla kan to wa loju ona Fasiti Adekunle Ajasin lo maa n duro si ni gbogbo igba.
E ka ekunrere ninu Alaroye ose yii

No comments:

Post a Comment