Orisiirisi aheso lo n lo bayii nipinle Osun, paapa laarin awon omo egbe oselu APC peluu bi ko se si oruko Omooba Olagunsoye Oyinlola ninu oruko awon merindinlogoji ti Aare Buhari fee lo gege bii minista re.
Ohun ti awon kan n so ni pe gomina tele funpinle Osun, to tun je asaaju egbe APC, Oloye Adebisi Akande lo wa nidi oro naa nitori pe oun lo fun Buhari ni oruko Ojogbon Isaac Adewole ti won mu bayii.
Bo tile je pe Ojogbon Adewole ti won pada mu ko dun mo Gomina Rauf Aregbesola ninu gege bi a se gbo, sibe ko si nnkan to le se lori e
Tuesday, 20 October 2015
Won ni Oloye Bisi Akande ni ko je ki Buhari mu Oyinlola gegebii minista
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment