Peluu bi wahala se po to lorii bi Aare Buhari se mu gomina tele funpinle Rivers, Rotimi Amaechi,
awon omo ile igbimo asofin agba ti so pe o peregede lati di minista lorileede yii.
Bo tile je pe gbogbo awon omo egbe oselu PDP ti won wa nile igbimo asofin agba ni won binu jade lati fehonu won han latari ohun ti won pe ni aitele ofin atilana nipa Amaechi, sibe aare ile, Bukola Saraki fi onte lu oruko Amaechi gege bii minista.
Thursday, 29 October 2015
Rotimi Amaechi Chibuike ti di minista
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment