IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 29 October 2015

Omo odun mokandinlogun ni Ooni tuntun nigba to bi akobi e

Ooni tuntun funlu Ileefe, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi, Ojaja 11 ti so pe omo odun mokandinlogun ni oun nigba ti Olorun fi akobi oun obinrin jinki oun.
Ogunwusi, eni to je Ooni to kere ju ati Ooni to ni baba laye ninu itan, ni akobi re pari
laipe yii ni University of Manchester to wa lorileede United Kingdom.

No comments:

Post a Comment