IROYIN YAJOYAJO

Sunday, 11 October 2015

Soyinka jawo ninu ibudo asa ile adulawo to wa nilu Osogbo


Ojogbon Wole Soyinka ti so pe oun ti yonda alaga ibudo asa ile adulawo to wa nilu Osogbo fun Omooba Olagunsoye Oyinlola.
Lati osu die seyin ni fa-n-fa ti n waye laarin Ojogbon Wole Soyinka ti Gomina Aregbesola yan gege bii alaga ibudo naa ati gomina ipinle Osun tele, Omooba Olagunsoye Oyinlola eni ti Ojogbon Ulli Beier to ni awon nnkan asa to wa nibudo naa fi se alaga laelae ibe.
Sugbon ni bayii, Soyinka ti so pe oun o se alaga ibudo naa mo.

No comments:

Post a Comment