Ni bayii to ku bii ojo meje ti Ooni Enitan Adeyeye Ogunwusi yoo jade ni Ilofi, Ogunsua ti ilu Modakeke ti sabewo idakonko sii ninu Ilofi to wa.
Ojoo Wesde ose yii la gbo pe Ogunsua, Oba Francis Adedoyin loo sepade pelu Ooni tuntun sugbon ti ko seni to mo nnkan ti won so nibe.
Bi awon kan se n so pe ipade naa ko lee seyin awon etutu kan to se koko gege bii ilu alamuleti, bee lawon kan n so pe lati le san ona fun irepo to dara laarin ilu mejeeji ni
Thursday, 12 November 2015
Ogunsua ti Modakeke sabewo si Ooni tuntun ninu Ilofi
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment