IROYIN YAJOYAJO

Monday, 16 November 2015

Mama HID ti bere irinajo sile ikeyin

Eto ayeye olojo mokanla ti won ti la kale fun eye ikeyin Oloogbe Oloye Hannah Dideolu Awolowo ti bere lana pelu tite nite eye nile Awolowo to wa ni Park Lane, Apapa nipinle Eko.
Lara awon ti won wa nibe lana ni gomina ipinle Eko atiyawo re, Senato Bola Tinubu, Pasito Matthew Ashimolowo, Oloye Ayo Adebajo, Erelu Olusola Obada ati bee bee lo.

No comments:

Post a Comment