IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 26 November 2015

Pupo ninu awon adajo ni ko nii dejoba orun - Yusuf Ali

Okan pataki lara awon agbejoro lorileede Naijiria, Yusuf Ali SAN ti so pe aisotito ni yoo ran opolopo awon adajo lo sinu ina.
Lasiko to n soro nibi eto kan tawon Islamic Welfare Foundation sagbateru e nilu Osogbo lo ti so pe opo adajo ti won maa n yi idajo po nitori owo tabi ohunkohun ni won ko nii dejoba orun.
O ni pupo won ni won mo nnkan to to sugbon won ko nii se e; won kun fun iwa jegudujera, won a si maa tumo ofin lona to wu won, eleyii to ni inu Oorun ko dun si.

No comments:

Post a Comment