Ese ko gbero lopin ose to koja nilu Itabo ni Lanlate nipinle Oyo nibi ti awon omo ati ojulumo oba ilu naa, HRM Oba Eyinloye Akano Afolabi (Ph.D), Amori keji ti korajo lati se eye ikeyin fun baba naa to waja lodun to koja.
Isin ale orin onigbagbo ni won fi bere laafin kabiesi naa lojoo Fraide, nibe si lopolopo eeyan ti jeri si igbesi aye baba naa gege bii eni to feran eko iwe.
Ileejosin First Baptist to wa nilu Itabo ni won ti sayeye idupe lojoo satide, ko too di pe awon eeyan loo je ajeyo lorii papa ti won ti gbalejo, leyin eyi ni Mega 99 kanlu si won nibadi.
Lara awon ti won wa nibe ni Oloye Gani Adams to waa ye okan lara awon ana oloogbe naa, Alao Adedayo tii se oludasile iweeroyin Alaroye si,
bee la tun ri Dokita Owoade pelu iyawo e ati osere tiata niin, Yomi Fash Lanso, atawon eeyan nlanla miin.
Sunday, 29 November 2015
Won ti se eye ikeyin fun Onitabo tilu Itabo to waja
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment