Metadinlogun ninu awon omo ile igbimo asofin meedogbon to wa nipinle Kogi ti so pe iwa wobia, ojukokoro, imotaraeni nikan ati sise owo basubasu lona taani yoo mu mi lo je kawon fowo osi juwe ile fun abenugan awon, Momoh Jimoh Lawal atigbakeji re, Aliyu Akuh.
Leyin ti won ye aga mo Lawal nidi tan ni won yan Godwin Osiyi Ojo gege bii abenugan tuntun, won si yan John Abah gege bii igbakeji re.
Leyin ti won ye aga mo Lawal nidi tan ni won yan Godwin Osiyi Ojo gege bii abenugan tuntun, won si yan John Abah gege bii igbakeji re.

No comments:
Post a Comment