IROYIN YAJOYAJO

Sunday, 13 December 2015

Naijiria gba ife eye awon agbaboolu tojo ori won ko tii to metalelogun nile Afrika


Egbe agbaboolu orileede yii ti ojo ori won ko tii to metalelogun labe idari Samson Siasia ti gba ife eye ile Afrika leyin ti won gbo ewuro soju awon akegbee won lati orileede Algeria pelu goolu meji si eyokan.
Oghenekaro Etebo ti orileede yii lo gba boolu mejeeji wole sinu awon Algeria nibi idije naa to waye ni Leopold Sedar Senghor Stadium, Dakar, nigba ti Segun Oduduwa ti orileede Algeria gba eyokansoso wole sodoo tiwa.

No comments:

Post a Comment