Leyin odun marun ti osere tiata ni, Muyideen Oladapo ti gbogbo aye mo si Lala ti wa nileewe Obafemi Awolowo University, Ile -Ife, idunnu lo je fun un loni pe o saseyori, o si keko gboye.
Eka imo Theatre Arts ni Lala ti kekogboye loni pelu ogunlogo awon akeko ti won jo pari.
No comments:
Post a Comment