Awon obinrin ilu Ileefe, paapa awon agbaagba ti won kun fun iriri ti seleri atileyin won fun iyawo Ooni, Olori Adebisi Adebukola Ogunwusi.
Won ni bi Olori naa tile kere lojo ori, sibe o ti di iya fun gbogbo awon obinrin ilu Ileefe bayii, ati pe gbogbo ona toun ati oko re, Ooni Enitan Adeyeye Ogunwusi, Ojaja Keji yoo gba saseyori nipo baba nla re lawon yoo maa san.

No comments:
Post a Comment