IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 3 February 2016

Eleha lawon olori (iyawo) Olowu ti Owu ile

Bo tile je pe oju otooto lawon eeyan miin fi wo ohun to sele nilu Owu Ile nijoba ibile Ejibo nipinle Osun laipe yii peluu bi oba won tuntun se jade pelu awon olori mejeeji to ni ti won je eleha, sibe awon onimo ninu esin Islam ti so pe ko si ohun to buru nibe.
Oba Muhammad Qozeem Rohji Adekunle Okikiola Ilufemiloye to gori ite awon baba nla re lomo odun mejidinlogoji lawon iyawo re mejeeji je eleha.

No comments:

Post a Comment