Adajo majistreeti kan nilu Osogbo ti pase pe ki omokunrin eni ogbon odun, Sulaiman Awokunle loo lo osu merin logba ewon ilu Ilesa lori esun pe o ji agbo gbe.
Bakan naa ladajo ni pelu poposinsin odun Ileya to n lo lowo, ko sanwo itanran egberun lona mefa naira.
Gege bi agbejoro funleese olopa, Inspekito Elijah Olusegun se so, ojo kejilelogun osu kejo odun yii ni Sulaiman ji agbo Saka Idowu lagboole Onurin nilu Iree nipinle Osun.
Leyin ti Sulaiman loun jebi esun naa ni agbejoro re, Okobie ro ile ejo lati faaye beeli sile fun un nitori pe se lo ro pe tie ni agbo naa to fi mu un so.
Amo sa, adajo majistreeti naa, Olowolagba Adenike so pe yala ki Sule lo osu merin logba ewon tabi ko san egberun lona mefa naira.
Thursday, 31 August 2017
N'Iree, won ni Sule ji agbo Saka, ladajo ba ni ko loo se Ileya logba ewon ilesa
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment