Okan pataki lara awon to n gbaradi lati dije funpo gomina ipinle Osun labe egbe oselu APC, Kunle Rasheed Adegoke ti so pe erongba okan Gomina Aregbesola ni lati gbe ipinle Osun doke tente sugbon aisi amojuto lori awon ise akanse to n se lo n fa ifaseyin diedie.
Lasiko ti Adegoke eni ti gbogbo eeyan mo si K-RAD n kopa nibi eto ti egbe oniroyin ipinle Osun sagbekale re lo ti ni amojuto to peye gbodo wa pelu ise akanse tijoba ba n se.
O fi kun oro re pe ti oun ba di gomina ipinle Osun, ko si ise akanse toun le gbe fawon agbasese toun ko nii maa mojuto ni gbogbo igba.
Nipaa pe awon eeyan ekun (senatorial) kan nipo gomina ipinle Osun kan, amofin yii ni ko si nnkan to jo bee ninu iwe ofin idibo orileede yii.
O ni iwa nii feeyan joye lawujo ati pe eni ti awon araalu ba fe ni yoo di gomina ipinle Osun lodun to n bo.
K-RAD ni inunibini lasan ni gbogbo ogun ti won n gbe dide si oludamoran lori eto ofin fegbe oselu APC lorileede yii, Muiz Banire ati pe idi otito
Friday, 8 September 2017
Erongba okan Aregbesola fawon eeyan ipinle Osun dara, sugbon..... - K-RAD
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Awa leyin yin, ema tesiwaju, Ki Olorun ran yin lowo
ReplyDelete