IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 5 October 2017

Ah! Chinedu, omo Poli gbe majele je tori pe o feeli idanwo

Ori lo ko okan lara awon omoleewe gbogbonise ipinle Nasarawa yo laipe yii nigba to gbe majele je, bi kii ba si se pe won tete gbe e lo sileewosan, eleko orun iba ti polowo fun un.
Lojo keji osu kewa yii la gbo pe Chinedu Iromuanya to wa ni eka isakoso, Public Administration gbe majele ohun je leyin to fidi remi ninu okan lara awon idanwo re.
A gbo pe inuu Chinedu ko dun fun bo tun se fidi remi ninu idanwo to ti se lati odun 2016 ohun.
Pelu ibinu lo fi gbe majele naa je, asiko to si n japoro iku lawon akeegbe re gbe e lo sileewosan  Dalhatu Araf Specialist Hospital ni Lafia.

No comments:

Post a Comment