Ohun gbogbo ti han kedere bayii pe afesona okan lara awon omo gomina ipinle Oyo, Seneto Abiola Ajimobi ni gbajugbaja omokunrin to n se DJ to doloogbe laipe yii, Olugbenga Abiodun ti gbogbo eeyan mo si DJ Olu.
Aheso lawon eeyan koko n pe oro naa tele, afigba ti Ajibola Ajimobi ko iwe edun sorii ero alatagba re nipa omokunrin afesona re ohun.
Atupale ohun ti Ajibola ko naa ni pe "Maa sinmi pelu irorun, ife mi. Maa so eso lorii mi, angeli mi".
Ojo keje osu kewa yii ni DJ Olu to je oreminu omokunrin olorin hiipu-hoopu nni, David Adeleke ti gbogbo eeyan mo si Davido Jade laye.
University of Essex ni Olu to je omo onisowo epo pataki nni, Deji Abiodun ti pari ko too di DJ fun Davido.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment