Tolulope Emmanuel, Osogbo
Owo ileese olopa ipinle Osun ti te Jimoh Sheriff omo ogun odun to je omobibi ilu Ifon-Osun eni to ni ile to fi n lu awon araalu ni jibiti.
Sheriff lo jewo pe oun pelu Alhaji kan, Afisu Olanipekun lawon jo n sise ninu ile naa.
Lara awon nnkan ti won ba ninu ile won lagbegbe Jamodo nilu Ifon Osun ni oogun abenugongo ti won fi n tan awon eeyan je atawon nnkan miin.
No comments:
Post a Comment