IROYIN YAJOYAJO

Tuesday, 31 October 2017

E wo awon agbaboolu Super Eagles ti yoo koju Algeria losu to n bo


Oluko akonimoogba fegbe agbaboolu Super Eagles ti orileede yii, Gernot  Rohr ti kede awon agbaboolu ti yoo kopa ninu idije ti won yoo ba orileede Algeria gba fun ipalemo Russia 2018.

Awon yen naa ni won yoo soju orileede yii nibi idije oloresore ti yoo waye pelu awon agbaboolu orileede Argentina losu kokanla bakan naa.

Awon agbaboolu ohun ati egbe agbaboolu ti won n sise fun loke-okun niwonyii:
Goalkeepers:
Daniel Akpeyi (Chippa United, South Africa), Ikechukwu Ezenwa (FC IfeanyiUbah) ati Francis Uzoho (Deportivo La Coruna, Spain)

Defenders:
William Ekong (Bursaspor FC, Turkey); Abdullahi Shehu (Anorthosis Famagusta, Cyprus); Tyronne Ebuehi (ADO Den Haag, The Netherlands); Leon Balogun (FSV Mainz 05, Germany), Uche Agbo (Standard Liege, Belgium),  Chidozie Awaziem (Nantes FC, France) ati  Olaoluwa Aina (Hull City, England)

Midfielders:
Mikel John Obi (Tianjin Teda, China), Ogenyi Onazi (Trabzonspor FC, Turkey); Wilfred Ndidi (Leicester City, England),  Oghenekaro Etebo (CD Feirense, Portugal); John Ogu (Hapoel Be’er Sheva, Israel); Mikel Agu (Bursaspor FC, Turkey) ati Chidiebere Nwakali (Sogndal FC, Norway)

Forwards:
Ahmed Musa (Leicester City, England); Kelechi Iheanacho (Leicester City, England); Moses Simon (KAA Gent, Belgium); Alex Iwobi (Arsenal FC, England); Odion Ighalo (Chang Chun-Yatai, China); Henry Onyekuru (RSC Anderlecht, Belgium) ati Anthony Nwakaeme (Hapoel Be’er Sheva, Israel)

STANDBY:
Kenneth Omeruo (Kasimpasa FC, Turkey); Alhassan Ibrahim (FK Austria Wien, Austria) ati  Brian Idowu (FC Amkar Perm, Russia).

Ojo kefa osu  kokanla odun yii lawon agbaboolu naa yoo pejo sorileede Morocco ki won too koja si Constantine lojoo Tosde ojo kesan osu kokanla kannaa.

Satide ojo kokanla ni baalu yoo gbe won lo si Krasnodar nibi idije oloresore peluu Argentina ti yoo waye lojo kerinla osu kokanla.

No comments:

Post a Comment