IROYIN YAJOYAJO

Tuesday, 31 October 2017

Ha ! Egbon Olamide, akeko OAU to ku ti soro o, o ni se ni won pa aburo oun


Tolulope Emmanuel, Osogbo

Otito miin tun ti fojuhan nipa akeko OAU to ku lose to koja, Mercy Olamide Afolahanmi pelu bi okunrin kan tawon eeyan gbagbo pe egbon re ni se ko oniruuru oro sorii feesibuuku nipa iku omobinrin eni odun merindinlogun naa.

Egbon Olamide ni ko si ooto ninu aheso pe se ni aburo oun pa araa re pelu oogun eku ati omi batiri nitorii pe ko se daada ninu idanwo. O ni ohun to wa leyin efa isele naa ju meje lo.

E ka awon nnkan to ko:



No comments:

Post a Comment