IROYIN YAJOYAJO

Monday, 30 October 2017

Hun ! E wo nnkan ti odidi gomina loo si fawon eeyan e


Akande Opeyemi



Iyalenu lo je fun gbogbo awon eeyan ipinle Ondo pe gomina won, Arakunrin Rotimi Akeredolu le ko awon lookolooko nile ijoba sodi loo si patako ijuwe ti won fi n polongo owo-fifo.

Idi si niyii tawon eeyan ko fi dekun sisoko oro sijoba pe se ara ereje ijoba tiwantiwa naa niyen.

No comments:

Post a Comment